Ísíkẹ́lì 44:5 BMY

5 Olúwa sì sọ fún mì pé, “Ọmọ ènìyàn, wò dáadáa, fetí sílẹ̀ dáadáa kí o sì fiyèsí ohun gbogbo tí mo sọ fún ọ nípa ofin lórí ilé Olúwa náà. Fiyèsí ẹnu ọ̀nà ilé Ọlọ́run náà àti gbogbo àbájáde ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:5 ni o tọ