Ísíkẹ́lì 45:21 BMY

21 “ ‘Ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìn-ín-ní ní ìwọ yóò ṣe àjọ ìrékọjá, àṣè ọjọ́ méje, àsìkò yìí ní ẹ̀yin yóò jẹ àkàrà tí kò ni ìwúkàrà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:21 ni o tọ