Ísíkẹ́lì 46:19 BMY

19 Lẹ́yìn náà ọkùnrin náà mú mi kọjá ní àbáwọlé tí ó wà lẹ́bá ẹnu ọ̀nà, sí àwọn yàrá mímọ́ tí ó kọjú sí ìhà àríwá, èyí tí ó jẹ́ tí àwọn àlùfáà, ó sì fi ibi kan hàn mí ní apá ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 46

Wo Ísíkẹ́lì 46:19 ni o tọ