Ísíkẹ́lì 46:3 BMY

3 Ní àwọn ọjọ́ ìsinmi àti àwọn oṣù tuntun ni kí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà jọ́sìn ní iwájú Olúwa ní àbáwọlé ẹnu ọ̀nà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 46

Wo Ísíkẹ́lì 46:3 ni o tọ