Ísíkẹ́lì 47:10 BMY

10 Àwọn apẹja yóò dúró ní etí bèbè odò; láti Éńgédì títí dé Énégíláémù àyè yóò wa láti tẹ́ àwọ̀n wọn sílẹ̀. Orísìírísìí ẹja ni yóò wà gẹ́gẹ́ bí ẹja omi òkun ńlá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:10 ni o tọ