Ísíkẹ́lì 47:17 BMY

17 Ààlà yóò fẹ̀ láti òkun lọ sí Hásà Énánù, ní apá ààlà ti Dámáskù, pẹ̀lú ààlà tí Hámátì lọ sí apá àríwá. Èyí ni yóò jẹ́ ààlà ní apá ìhà àríwá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:17 ni o tọ