Ísíkẹ́lì 47:2 BMY

2 Ó wá mú mi gba ojú ọ̀nà àríwá jáde, ó sì mú mi yí ìta ojú ọ̀nà ìta tí ó dojúkọ ìhà ìlà oòrùn, omi náà sì ń ṣàn láti ìhà gúsù wá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:2 ni o tọ