Ísíkẹ́lì 47:20 BMY

20 “Ní ìhà ìwọ̀ oòrùn, òkun ńlá ni yóò jẹ́ ààlà títí dé ibi kan ni òdìkejì lẹ́bàá Hámátì. Èyí yìí ni yóò jẹ ààlà ìhà ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:20 ni o tọ