Ísíkẹ́lì 48:22 BMY

22 Ilẹ̀ ìní àwọn Léfì àti ohun ìní ìlú ńlá náà yóò wà ni àárin agbégbé tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ aládé. Agbégbé tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ aládé yóò wà ní àárin ààlà tí Júdà àti ààlà tí Bénjámínì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:22 ni o tọ