Ísíkẹ́lì 48:33 BMY

33 “Ní ìhà gúsù, èyí tí wíwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lè ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (4,500) ìgbọ̀nwọ́ ní ojú ọ̀nà mẹ́ta yóò wà: ojú ọ̀nà Símónì, ojú ọ̀nà Ísákárì àti ojú ọ̀nà Sébúlónì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:33 ni o tọ