Ísíkẹ́lì 7:16 BMY

16 Gbogbo àwọn tí ó bọ́ nínú wọn yóò sálà, wọn yóò sì wà lórí òkè bí i àdàbà inú àfonífojì, gbogbo wọn yóò máa ṣọ̀fọ̀, olúkúlùkù nítorí àìṣedédé rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:16 ni o tọ