Ísíkẹ́lì 8:1 BMY

1 Ní ọjọ́ karùn-ún (5), oṣù kẹfà (6) ọdún kẹfà (6) bí mo ṣe jókòó nílé mi pẹ̀lú àwọn àgbààgbà Júdà níwájú mi, ọwọ́ Olúwa Ọlọ́run bà lé mi níbẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:1 ni o tọ