Ísíkẹ́lì 9:1 BMY

1 Mo gbọ́ tó kígbe pé, “Mú àwọn olùṣọ́ ìlú súnmọ́ ìtòsí, kí olúkúlùkù wọn mú ohun ìjà olóró lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 9

Wo Ísíkẹ́lì 9:1 ni o tọ