Ísíkẹ́lì 9:3 BMY

3 Ògo Ọlọ́run sì gòkè kúrò lórí Kérúbù, níbi tó wà tẹ́lẹ̀ lọ síbi ìloro tẹ́ḿpìlì. Nígbà náà ni Olúwa pe ọkùnrin tó wọ aṣọ funfun lẹlẹ tí ó sì ní ohun ìkọ̀wé lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 9

Wo Ísíkẹ́lì 9:3 ni o tọ