Ísíkẹ́lì 9:8 BMY

8 Èmi nìkan ló ṣẹ́kù nígbà tí wọ́n lọ pa àwọn ènìyàn mo dójú bolẹ̀, mo kígbe pé, “Áà! Olúwa Ọlọ́run! Ìwọ yóò ha pa ìyókù Ísírẹ́lì pẹ̀lú dída ìbínú gbígbónà rẹ sórí Jérúsálẹ́mù?”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 9

Wo Ísíkẹ́lì 9:8 ni o tọ