Onídájọ́ 1:6 BMY

6 Ọba Adoni-Bésékì sá àṣálà, ṣùgbọ́n ogun Ísírẹ́lì lépa rẹ̀ wọ́n sì bá a, wọ́n sì gé àwọn àtàǹpàkò ọwọ́ àti ẹṣẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:6 ni o tọ