Onídájọ́ 11:19 BMY

19 “Nígbà náà ni Ísírẹ́lì rán àwọn oníṣẹ́ sí Síhónì ọba àwọn ará Ámórì, ẹni tí ń ṣe àkóso ní Hésíbónì, wọ́n sì wí fún un pé, ‘Jẹ́ kí a la ilẹ̀ rẹ kọja lọ sí ibùgbé wa.’

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:19 ni o tọ