Onídájọ́ 11:6 BMY

6 Wọ́n wí fún Jẹ́fità wí pé, “Wá kí o sì jẹ́ olórí ogun wa kí a lè kọjú ogun sí àwọn ará Ámónì.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:6 ni o tọ