Onídájọ́ 14:10 BMY

10 Baba rẹ̀ sì sọ̀kalẹ̀ lọ láti kí obìnrin náà. Sámúsónì sì ṣe àṣè gẹ́gẹ́ bí àṣà ọkọ ìyàwó ní àkókò náà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 14

Wo Onídájọ́ 14:10 ni o tọ