Onídájọ́ 15:17 BMY

17 Nígbà tí ó dákẹ́ ọ̀rọ̀ ísọ, ó ju egungun àgbọ̀n ìṣàlẹ̀ náà nù, wọ́n sì pe ibẹ̀ ní Ramati-Léhì (ìtúmọ̀ rẹ̀ jẹ́ egungun àgbọ̀n ìṣàlẹ̀ pa).

Ka pipe ipin Onídájọ́ 15

Wo Onídájọ́ 15:17 ni o tọ