Onídájọ́ 17:10 BMY

10 Míkà sì sọ fún un wí pé, “Dúró lọ́dọ̀ mi (máa bá mi gbé) kí ìwọ sì jẹ́ baba mi àti àlùfáà fún mi, èmi ó sì máa fún ọ ní ṣékélì mẹ́wàá fàdákà ní ọdọọdún, pẹ̀lú aṣọ àti oúnjẹ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 17

Wo Onídájọ́ 17:10 ni o tọ