Onídájọ́ 19:12 BMY

12 Ọ̀gá rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Rárá o, àwa kì yóò wọ ìlú àwọn àjèjì, àwọn tí olùgbé ibẹ̀ kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì, a ó ò dé Gíbíà.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:12 ni o tọ