Onídájọ́ 19:20 BMY

20 “Mo kí ọ kú ààbọ̀ sí ilé mi,” ni ìdáhùn ọkùnrin arúgbó náà. “Èmi yóò pèṣè gbogbo ohun tí o nílò, kìkì pé kí ìwọ má ṣe sun ìta.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:20 ni o tọ