Onídájọ́ 19:4 BMY

4 Àna rẹ̀, baba ọmọbìnrin náà rọ̀ ọ́, ó sì borí rẹ̀ láti dá a dúró fún ìgbà díẹ̀, òun sì dúró fún ọjọ́ mẹ́ta, ó ń jẹ, ó ń mu, ó sì ń sùn níbẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:4 ni o tọ