Onídájọ́ 19:6 BMY

6 Àwọn méjèèjì sì jùmọ̀ jókòó wọn láti jọ jẹun àti láti jọ mu. Lẹ́yìn èyí ni baba ọmọbìnrin wí pé, “Jọ̀wọ́ dúró ní alẹ́ yìí kí o sì gbádùn ara rẹ.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:6 ni o tọ