Onídájọ́ 2:1 BMY

1 Ní ọjọ́ kan ańgẹ́lì Olúwa dìde kúrò láti Gígálì lọ sí Bókímù ó sì wí pé, “Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Éjíbítì wá, èmi sì ṣíwájú yín wá sí ilẹ̀ tí mo ti ṣèlérí láti fi fún àwọn baba ńlá yín. Èmi sì wí pé, ‘Èmi kì yóò yẹ májẹ̀mú mi pẹ̀lú yín.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 2

Wo Onídájọ́ 2:1 ni o tọ