Onídájọ́ 20:22 BMY

22 Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì mú ara wọn lọ́kàn le, wọ́n sì tún dúró sí ipò wọn ní ibi tí wọ́n dúró sí ní ọjọ́ àkọ́kọ́.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:22 ni o tọ