Onídájọ́ 20:25 BMY

25 Ní ọjọ́ yìí nígbà tí ará Bẹ́ńjámínì jáde sí wọn láti Gíbíà, láti dojú kọ wọn, wọ́n pa ẹgbẹ̀sán (18,000) ọkùnrin Ísírẹ́lì, gbogbo wọn jẹ́ jagunjagun tí ń lo idà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:25 ni o tọ