Onídájọ́ 20:32 BMY

32 Nígbà tí àwọn Bẹ́ńjámínì ń wí pé, “Àwa ti ń ṣẹ́gun wọn bí i ti ìṣáájú,” àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a sá kí a lè fà wọ́n kúrò ní ìlú sí ojú òpópó náà.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:32 ni o tọ