Onídájọ́ 20:5 BMY

5 Ṣùgbọ́n ní òru àwọn ọkùnrin Gíbíà lépa mi wọ́n sì yí ilé náà po pẹ̀lú èrò láti pa mí. Wọ́n fi ipá bá àlè mi lòpọ̀, òun sì kú.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:5 ni o tọ