Onídájọ́ 21:2 BMY

2 Àwọn ènìyàn náà lọ sí Bẹ́tẹ́lì: ilé Ọlọ́run, níbi tí wọ́n jókòó níwájú Ọlọ́run títí di àṣálẹ́, wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì sunkún kíkorò.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 21

Wo Onídájọ́ 21:2 ni o tọ