Onídájọ́ 3:30 BMY

30 Ní ọjọ́ náà ni Ísírẹ́lì ṣẹ́gun àwọn ará Móábù, ilẹ̀ náà sì wà ní àlàáfíà fún ọgọ́rin ọdún.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 3

Wo Onídájọ́ 3:30 ni o tọ