Onídájọ́ 5:27 BMY

27 Ní ẹṣẹ̀ rẹ̀, ó wólẹ̀ó ṣubú; ó dúbúlẹ̀.Ní ẹṣẹ̀ rẹ̀, ó wó lulẹ̀;ní ibi tí ó gbé wólẹ̀ sí, níbẹ̀ náà ni ó ṣubú kú.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 5

Wo Onídájọ́ 5:27 ni o tọ