Onídájọ́ 6:1 BMY

1 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì tún ṣe ohun tí ó burú ní ojú Olúwa, Ó sì fi wọ́n lé àwọn ará Mídíánì lọ́wọ́ fún ọdún méje.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:1 ni o tọ