Onídájọ́ 6:21 BMY

21 Ańgẹ́lì Olúwa sì fi orí ọ̀pá tí ó wà ní ọwọ́ rẹ̀ kan ẹran àti àkàrà àìwú náà. Iná sì jáde láti inú àpáta, ó sì jó ẹran àti àkàrà náà, kò sì rí ańgẹ́lì náà mọ́.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:21 ni o tọ