Onídájọ́ 6:35 BMY

35 Ó rán àwọn oníṣẹ́ la ilẹ̀ Mánásè já pé kí wọ́n dira ogun, àti sí Ásérì, Ṣébúlúnì àti Náfítalì gbogbo pẹ̀lú sì lọ láti pàdé wọn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:35 ni o tọ