Onídájọ́ 6:8 BMY

8 Olúwa fi etí sí igbe wọn, ó sì rán wòlíì kan sí wọn. Ẹni tí ó wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: mo mú yín gòkè ti Éjíbítì wá, láti oko ẹrú.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:8 ni o tọ