Onídájọ́ 7:23 BMY

23 Gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì láti ẹ̀yà Náfítalì, Ásérì àti gbogbo Mànásè ni Gídíónì ránṣẹ́ sí, wọ́n wá wọ́n sì lé àwọn ará Mídíánì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:23 ni o tọ