Onídájọ́ 8:16 BMY

16 Ó mú àwọn àgbààgbà ìlú náà, ó sì fi kọ́ àwọn Ṣúkótì lọ́gbọ́n nípa jíjẹ wọ́n níyà pẹ̀lú àwọn ẹ̀gún aṣálẹ̀ àti ẹ̀gún ọ̀gàn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:16 ni o tọ