Onídájọ́ 8:19 BMY

19 Gídíónì dáhùn pé, “Arákùnrin mi ni wọ́n, àwọn ọmọ ìyá mi. Mo fi Olúwa búra, bí ó bá ṣe pé ẹ dá ẹ̀mí wọn sí, èmi náà ò ní pa yín.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:19 ni o tọ