Onídájọ́ 8:2 BMY

2 Ṣùgbọ́n Gídíónì dá wọn lóhùn pé, “Àṣeyọrí wo ni mo ti ṣe tí ó tó fi wé tiyín? Àṣàkù àjàrà Éfúráímù kò ha dára ju gbogbo ìkórè àjàrà Ábíésérì lọ bí?

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:2 ni o tọ