Onídájọ́ 8:32 BMY

32 Gídíónì ọmọ Jóásì kú ní ògbólógbó ọjọ́ rẹ̀, ó sì pọ̀ ní ọjọ́ orí, wọ́n sì sin-ín sí ibojì baba rẹ̀ ní Ófírà ti àwọn ará Ábíésérì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:32 ni o tọ