Onídájọ́ 8:34 BMY

34 Wọn kò sì rántí Olúwa Ọlọ́run wọn, ẹni tí ó gbà wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀ta wọn gbogbo tí ó wà ní gbogbo àyíká wọn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:34 ni o tọ