Onídájọ́ 8:5 BMY

5 Ó wí fún àwọn ọkùnrin Ṣúkótì pé, “Ẹ fún àwọn ọmọ ogun mi ní oúnjẹ diẹ̀, nítorí ó ti rẹ̀ wọ́n, èmi sì ń lépa Ṣébà àti Ṣálímúnà àwọn ọba Mídíánì.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:5 ni o tọ