Onídájọ́ 8:8 BMY

8 Láti ibẹ̀, ó lọ sí Péníélì ó sì bẹ̀ wọ́n bẹ́ ẹ̀ gẹ́gẹ́, ṣùgbọ́n àwọn náà dá a lóhùn bí àwọn ará Súkótì ti dá a lóhùn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:8 ni o tọ