Onídájọ́ 9:25 BMY

25 Nítorí ìkórira tí wọ́n ni sí àwọn olórí, ni Ṣékémù dẹ àwọn ènìyàn sí àwọn orí òkè láti máa dá àwọn ènìyàn tó ń kọja lọ́nà, kí wọn sì máa jà wọ́n lólè, àwọn kan ló sọ èyí fún Ábímélékì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:25 ni o tọ