Onídájọ́ 9:35 BMY

35 Gáálì ọmọ Ébédì jáde síta, ó sì dúró ní ẹnu ọ̀nà ibodè ìlú náà ní àkókò tí Ábímélékì àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jáde kúrò níbi tí wọn sá pamọ́ sí.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:35 ni o tọ