Onídájọ́ 9:9 BMY

9 “Ṣùgbọ́n igi Ólífì dá wọn lóhùn pé, ‘Èmi yóò ha fi òróró mi sílẹ̀ èyí tí a ń lò láti fi ọ̀wọ̀ fún àwọn ọlọ́run àti ènìyàn kí èmi sì wá ṣolórí àwọn igi?’

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:9 ni o tọ