Lúùkù 1:41 BMY

41 Ó sì ṣe, nígbà tí Èlísábẹ́tì gbọ́ kíkí Màríà, ọlẹ̀ sọ nínú rẹ̀; Èlísábẹ́tì sì kún fún Èmí mímọ́;

Ka pipe ipin Lúùkù 1

Wo Lúùkù 1:41 ni o tọ