Lúùkù 1:63 BMY

63 Ó sì béèrè fún wàláà, ó sì kọ ọ wí pé, “Jòhánù ni orúkọ rẹ̀.” Ẹnu sì ya gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Lúùkù 1

Wo Lúùkù 1:63 ni o tọ